Jeremáyà 51:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀run àti ayé àti gbogbo ohun tí ó wà nínú wọn,yóò sì kọrin lórí Bábílónì:nítorí àwọn afiniṣèjẹ yóò wá sórí rẹ̀ láti àríwá,”ni Olúwa wí.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:39-52