Jeremáyà 51:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìgbà náà yóò wádandan nígbà tí èmiyóò fi ìyà jẹ àwọnòrìṣà Bábílónì, gbogbo ilẹ rẹ̀ ni a ó dójú tìgbogbo àwọn tí a pa yóò sì ṣubú ní àárin rẹ̀.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:43-49