Jeremáyà 51:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ wárìrì síhìn ín sọ́hùn ún, nítorí péète Olúwa, sí Bábílónì dúróláti ba ilẹ̀ Bábílónì jẹ́ lọ́nàtí ẹnikẹ́ni kò ní lè gbé inú rẹ̀ mọ́.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:19-35