Jeremáyà 51:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo lòdì sí ọ, ìwọ òkè apanirunìwọ ti ba gbogbo ayé jẹ́,”ni Olúwa wí.“Èmi ó na ọwọ́ mi sí ọ,èmi yóò yí ọ kúrò lórí àpáta,Èmi yóò sọ ọ́ dàbí òkè tí a ti jó.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:21-26