Jeremáyà 51:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ojú rẹ, èmi yóò san án fún Bábílónì àti gbogbo àwọn olùgbé inú rẹ̀ fún gbogbo ibi tí wọ́n ti ṣe ní Síónì,”ni Olúwa wí.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:20-33