Jeremáyà 51:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ó dá ilẹ̀ nípa agbára rẹ̀,o dá ilẹ̀ ayé pẹ̀lú ọgbọ́n rẹ̀,o sì tẹ́ ọ̀run pẹ̀lú ìmọ̀ rẹ̀.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:6-18