Jeremáyà 51:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti búra fún ara rẹ̀,Èmi yóò fún ọ ní ènìyàn gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ eṣú,wọn yóò yọ ayọ̀, iṣẹ́gun lórí rẹ.

Jeremáyà 51

Jeremáyà 51:10-22