Jeremáyà 49:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sálọ kíákíá, dúró nínú ihòìwọ tí ò ń gbé Ásórì,”báyìí ni Olúwa wí.“Nebukadinésárì Ọba Bábílónì ti dojú ìjà kọ ọ́.

Jeremáyà 49

Jeremáyà 49:23-34