Jeremáyà 49:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àgọ́ wọn àti agbo àgùntàn wọnyóò di gbígbà; ilé wọn yóò diìsínípò padà pẹ̀lú ẹrù àti ràkúnmí wọn.Àwọn ọkùnrin yóò ké pè wọ́n;‘Ìparun ní ibi gbogbo.’

Jeremáyà 49

Jeremáyà 49:27-34