Jeremáyà 47:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gásà yóò fá irun orí rẹ̀ nínú ọ̀fọ̀.A ó pa Áṣíkélónì lẹ́nu mọ́;ìyókù ní pẹ̀tẹ́lẹ̀,ìwọ yóò ti ṣá ara rẹ lọ́gbẹ́ pẹ́ tó?

Jeremáyà 47

Jeremáyà 47:4-6