Jeremáyà 45:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé ìwọ yóò wá ohun rere fún ara rẹ? Nítorí náà, má ṣe wá wọn. Èmi yóò mú ibi wá sí orí àwọn ènìyàn gbogbo ni Olúwa wí. Níbikíbi tí o bá lọ ni èmi yóò jẹ́ kí o sá àsálà ẹ̀mí rẹ ní àlàáfíà.’ ”

Jeremáyà 45

Jeremáyà 45:1-5