Jeremáyà 45:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa wí pé sọ èyí fún un, “Èyí ni Ọlọ́run sọ: ‘Èmi yóò sí ipò àwọn ohun tí mo ti kọ àti pé: Èmi yóò wú àwọn nǹkan tí mo gbìn sí orí ilẹ̀ náà.

Jeremáyà 45

Jeremáyà 45:1-5