Jeremáyà 44:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún ìdí èyí, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run àwọn Ísírẹ́lì wí: Mo ti pinnu láti mú ibi wá sí orí yín àti láti pa Júdà run.

Jeremáyà 44

Jeremáyà 44:8-16