Jeremáyà 44:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìgbà náà sí àkókò yìí, wọn kò rẹ ara wọn sílẹ̀ tàbí fi ìtẹ́ríba hàn tàbí kí wọn ó tẹ̀lé òfin àti àṣẹ tí mo pa fún un yín àti àwọn baba yín.

Jeremáyà 44

Jeremáyà 44:4-16