Jeremáyà 42:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti sọ fún un yín lónìí, ṣùgbọ́n síbẹ̀ ẹ̀yin kò tí ì gbọ́ ohùn Olúwa Ọlọ́run yín, àti gbogbo ohun tí ó rán mi láti sọ fún un yín.

Jeremáyà 42

Jeremáyà 42:11-22