Jeremáyà 42:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pé àṣìṣe ńlá gbáà ni ẹ̀yin ṣe nígbà tí ẹ̀yin rán mi sí Olúwa Ọlọ́run yín pé, ‘Gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run wa fún wa; sọ fún wa gbogbo ohun tí ó bá sọ, àwa yóò sì ṣe é.’

Jeremáyà 42

Jeremáyà 42:17-22