Jeremáyà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi àmì láti sálọ sí Síónì hàn,sálọ fún ààbò láìsí ìdádúró.Nítorí èmi ó mú àjálù láti àríwá wá,àní ìparun tí ó burú jọjọ.”

Jeremáyà 4

Jeremáyà 4:1-9