Jeremáyà 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kéde ní Júdà, kí o sì polongo ní Jérúsálẹ́mù, kí o sì wí pé:‘fun fèrè káàkiri gbogbo ilẹ̀. Kí o sì kígbe,‘kó ara jọ pọ̀!Jẹ́ kí a sálọ sí ìlú olódi.’

Jeremáyà 4

Jeremáyà 4:1-9