Jeremáyà 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó! O ń bò bí ìkuukùukẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ sì wá bí ìjì líleẸ̀ṣin rẹ̀ sì yára ju idì lọÈgbé ni fún wa àwa parun.

Jeremáyà 4

Jeremáyà 4:10-16