Jeremáyà 38:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Sedekáyà sọ fún Jeremáyà pé, “Má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ nípa ọ̀rọ̀ yìí, tàbí kí o kú.

Jeremáyà 38

Jeremáyà 38:18-26