Jeremáyà 38:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wọn yóò kó àwọn ìyàwó àti ọmọ rẹ wá sí Bábílónì. Ìwọ gan-an kò ní bọ́ níbẹ̀, Ọba Bábílónì yóò mú ọ, wọn yóò sì jó ìlú yìí kanlẹ̀.”

Jeremáyà 38

Jeremáyà 38:14-28