Jeremáyà 38:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ebedimélékì sọ fún Jeremáyà pé, “Fi àkísà àti okùn bọ abẹ́ abíyá rẹ, Jeremáyà sì ṣe bẹ́ẹ̀.”

Jeremáyà 38

Jeremáyà 38:4-18