Jeremáyà 38:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ebedimélékì kó àwọn ọkùnrin náà pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n lọ sínú yàrá kan nínú ààfin Ọba. Ó mú àwọn aṣọ àkísà àti okùn tọ Jeremáyà lọ nínú àmù.

Jeremáyà 38

Jeremáyà 38:5-20