Jeremáyà 38:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sefatíà ọmọ Mátanì, Gédáyà ọmọ Páṣúrì, Jéhúdù ọmọ Selemáyà àti Páṣúrì ọmọ Málíkíà gbọ́ ohun tí Jeremáyà ń sọ fún àwọn ènìyàn nígbà tí ó sọ wí pé,

Jeremáyà 38

Jeremáyà 38:1-10