Jeremáyà 37:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Sedekáyà wá pàṣẹ pé kí wọ́n fi Jeremáyà sínú àgbàlá àwọn ẹ̀ṣọ́, àti kí wọn sì fún ní àkàrà ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan títí tí àkàrà yóò fi tán; bẹ́ẹ̀ ni Jeremáyà wà nínú àgbàlá náà.

Jeremáyà 37

Jeremáyà 37:11-21