Jeremáyà 37:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n bínú sí Jeremáyà, wọ́n jẹ ẹ́ níyà, wọ́n tún fi sí àtìmọ́lé nílé Jónátanì akọ̀wé nítorí wọ́n ti fi èyí ṣe ilé túbú.

Jeremáyà 37

Jeremáyà 37:9-19