Jeremáyà 37:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jeremáyà sọ wí pé, “Èyí kì í ṣe òtítọ́! Èmi kò yapa sí àwọn ará Bábílónì.” Ṣùgbọ́n Íríjà kọ tí ikún sí i, dípò èyí a mú Jeremáyà, ó sì mú un lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ìjòyè.

Jeremáyà 37

Jeremáyà 37:8-15