Jeremáyà 36:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mú ìwé kíká fún ará rẹ, kí o sì kọ sínú rẹ̀ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo ti sọ nípa Ísírẹ́lì àti ti Júdà, àti sí gbogbo orílẹ̀ èdè láti ìgbà tí mo ti sọ fún ọ láti ọjọ́ Jòsáyà títí di òní.

Jeremáyà 36

Jeremáyà 36:1-12