Jeremáyà 32:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sedekáyà Ọba Júdà kò lè bọ́ lọ́wọ́ àwọn Kálídéà, ṣùgbọ́n à ó mú fún Ọba Bábílónì, yóò sì bá sọ̀rọ̀ ní ojúkojú; yóò sì rí pẹ̀lú ojú rẹ̀.

Jeremáyà 32

Jeremáyà 32:3-6