Jeremáyà 32:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Sedekáyà Ọba Júdà ti há a mọ́lé síbẹ̀; pé, “Kí ló dé tí ìwọ fi ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ báyẹn? Tí o sì wí pé, ‘Báyìí ni Olúwa wí: Èmi ń bọ̀ wá fi ìlú yìí fún Ọba Bábílónì, tí yóò sì gbà á.

Jeremáyà 32

Jeremáyà 32:1-13