Jeremáyà 31:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà náà, Èmi yóò jẹ́ Ọlọ́run fún gbogbo ìdílé ìran Ísírẹ́lì, àwọn náà yóò sì jẹ́ ènìyàn mi,” ni Olúwa wí.

Jeremáyà 31

Jeremáyà 31:1-5