Jeremáyà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Padà, ẹ̀yin ènìyàn aláìnígbàgbọ́,” ni Olúwa wí, “nítorí èmi ni ọkọ rẹ. Èmi ó yàn ọ́, ọ̀kan láti ìlú àti méjì láti ẹ̀yà. Èmi ó sì mú ọ wá sí Síónì.

Jeremáyà 3

Jeremáyà 3:12-23