Jeremáyà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sá à ti mọ ẹ̀bi rẹ,o ti ṣọ̀tẹ̀ sí Olúwa Ọlọ́run rẹ,o ti wá ojú rere rẹ lọ́dọ̀ ọlọ́run àjèjìlábẹ́ gbogbo igikígi,tí ó tẹ́wọ́, o kò sì gbọ́ràn sí mi lẹ́nu,’ ”ni Olúwa wí.

Jeremáyà 3

Jeremáyà 3:6-21