Jeremáyà 28:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ níwájú gbogbo ènìyàn wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa wí: ‘Bákan náà ni mà á fọ́ àjàgà ọrùn Nebukadinésárì, Ọba Bábílónì láàrin ọdún méjì.’ ” Jeremáyà sì bá ọ̀nà tirẹ̀ lọ.

Jeremáyà 28

Jeremáyà 28:9-12