Jeremáyà 26:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti tí ẹ kò bá fetísí àwọn ọ̀rọ̀ yìí tí àwọn ìránṣẹ́ mi, àwọn wòlíì tí mo rán sí i yín: bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ kò fetí sílẹ̀.

Jeremáyà 26

Jeremáyà 26:3-6