Jeremáyà 25:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, èmi ń mú ibi bọ̀ sí orí orílẹ̀ èdè tí ó ń jẹ́ orúkọ mi; ǹjẹ́ yóò há a lè lọ láìjìyà? Ẹ̀yin ń pe idà sọ̀kalẹ̀ sórí gbogbo àwọn olùgbé ayé, ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ.’

Jeremáyà 25

Jeremáyà 25:27-32