Jeremáyà 2:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbẹ̀ nínú gbogbo èyíìwọ sọ wí pé, ‘Èmi jẹ́ aláìsẹ̀kò sì bínú sími.’Èmi yóò ṣe ìdájọ́ mi lórí rẹnítorí pé ìwọ sọ pé, ‘Èmi kò tí ìdẹ́sẹ̀.’

Jeremáyà 2

Jeremáyà 2:30-36