Jeremáyà 2:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ̀ mí wá wí pé:

2. “Lọ kéde sí etí ìgbọ́ àwọn Jérúsálẹ́mù:“ ‘Mo rántí ìfarasìn ìgbà èwe rẹ,gẹ́gẹ́ bí o ṣe nífẹ̀ẹ́ mi bí i wúndíá àti bí o ṣe tẹ̀lé mi nínú aṣálẹ̀ àti nínú ìyàngbẹ ilẹ̀.

3. Ísírẹ́lì jẹ́ mímọ́ sí Olúwa, àkọ́kọ́èṣo ìkórè rẹ̀, gbogbo ẹnikẹ́ni tí óbá jẹ run ni a ó dá lẹ́bi, ìpọ́njúyóò dé bá wọn,’ ”bẹ́ẹ̀ ni Olúwa wí.

Jeremáyà 2