Jeremáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísírẹ́lì jẹ́ mímọ́ sí Olúwa, àkọ́kọ́èṣo ìkórè rẹ̀, gbogbo ẹnikẹ́ni tí óbá jẹ run ni a ó dá lẹ́bi, ìpọ́njúyóò dé bá wọn,’ ”bẹ́ẹ̀ ni Olúwa wí.

Jeremáyà 2

Jeremáyà 2:1-8