Jeremáyà 15:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò gbà ọ́ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọnìkà ènìyàn, Èmi yóò sì rà ọ́padà kúrò lọ́wọ́ àwọn ẹni búburú.”

Jeremáyà 15

Jeremáyà 15:19-21