Jeremáyà 15:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

È é ṣe tí ìrora mi kò lópin, tí ọgbẹ́mi ń nira tí kò sì ṣe é wòsàn?Ṣe ìwọ yóò dàbí kànga ẹ̀tàn sí mi,gẹ́gẹ́ bí ìsun tó kọ̀ tí kò sun?

Jeremáyà 15

Jeremáyà 15:15-21