Jeremáyà 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò fìgbà kan jókòó láàrin àwọn ẹlẹ́gàn.Má ṣe bá wọn yọ ayọ̀ pọ̀;mo dá jókòó torí pé ọwọ́ rẹ wàlára mi, ìwọ sì ti fi ìbínú rẹ kún inú mi.

Jeremáyà 15

Jeremáyà 15:11-21