Jeremáyà 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéṣe tí ìwọ dàbí ẹni tí a mú lójijì pẹ̀lú ìyan,bí jagunjagun tí kò lágbára láti gba ni?Ìwọ wà láàárin wa, Olúwa,orúkọ rẹ ni a sì ń jẹ́;má ṣe fi wá sílẹ̀.

Jeremáyà 14

Jeremáyà 14:1-10