Jeremáyà 14:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìrètí Ísírẹ́lì;ìgbàlà rẹ lásìkò ìpọ́njú,èéṣe tí ìwọ dàbí àlejò ní ilẹ̀ náàbí arìnrìnàjò tí ó dúró fún bí òru ọjọ́ kan péré?

Jeremáyà 14

Jeremáyà 14:7-12