Jeremáyà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí o bá sì bi ara rẹ léèrè“Kí ni ìdí rẹ̀ tí èyí fi ṣẹlẹ̀ sí mi?”Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ tí o ṣẹ̀ni aṣọ rẹ fi fàyatí a sì ṣe é ní ìṣekúṣe.

Jeremáyà 13

Jeremáyà 13:19-26