Jeremáyà 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ni ìwọ yóò wí nígbà tí Olúwa bá dúró lórí rẹàwọn tí o mú bí ọ̀rẹ́ àtàtà.Ǹjẹ́ kò ní jẹ́ ìrora fún ọbí aboyún tó ń rọbí?

Jeremáyà 13

Jeremáyà 13:16-24