Jeremáyà 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Má ṣe gbàdúrà fún àwọn ènìyàn wọ̀nyí tàbí kí o bẹ̀bẹ̀ fún wọn, nítorí pé Èmi kò ní dẹtí sí wọn ní ìgbà ìpọ́njú.

Jeremáyà 11

Jeremáyà 11:10-16