Jeremáyà 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí iye àwọn ìlú yín ṣe pọ̀ tó náà ni àwọn òrìṣà yín. Ìwọ Júdà: àwọn pẹpẹ tí o ti pèsè fún jíjó tùràrí sí àwọn Báálì, òrìṣà yẹ̀yẹ́ sì pọ̀ bí iye òpópó tí ó wà ní Jérúsálẹ́mù.’

Jeremáyà 11

Jeremáyà 11:9-20