Jeremáyà 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni kò yẹ kí ó bẹ̀rù rẹ Ọba àwọnorílẹ̀ èdè? Nítorí tìrẹ ni, láàrin àwọnọlọ́gbọ́n ènìyàn ní orílẹ̀ èdè àtigbogbo ìjọba wọn, kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ.

Jeremáyà 10

Jeremáyà 10:6-13