Jeremáyà 10:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ Olúwa;o tóbi orúkọ rẹ sì tóbi lágbára.

Jeremáyà 10

Jeremáyà 10:1-9